Ìtumọ̀ mu | Babel Free
mũ̄Àwọn ìtumọ̀
Àwọn àpẹẹrẹ
“Má mu ọtí tó o bá fẹ́ wakọ̀.”
Don't drink alcohol if you want to drive.
“Ọmọ-ọwọ́ ṣì ń mu ọmú.”
The baby is still sucking breast.
“Ọmọdé ń mu ọsàn.”
The child is licking orange.
“Kò kí ń mu sìgá.”
She doesn't smoke cigarettes.
“Àwọn ọlọ́pàá ti mú wa o.”
The police have caught us!
“Mo mú bọ́ọ̀lù.”
I caught the ball.
“Òtútù ń mú mi.”
I feel cold.
“Oògùn yẹn mú mi sùn.”
That drug made me sleep.
“Ó mú mi mumi.”
It made me drink water.
“Ọbẹ̀ náà mú.”
That knife is sharp.
“Ó mù sábẹ́ igbó.”
It's hidden under the bush.
“Méè mù .”
I don't know .
Ìpele CEFR
C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free