Ìtumọ̀ na | Babel Free
nã́Àwọn ìtumọ̀
Àwọn àpẹẹrẹ
“Ó nà án ní pàṣán”
She beat him with a whip
“Àníkẹ́ ń ná owó nínàákúkàá”
Anike is spending money extravagently
“Ó ná mi ní ogún náírà péré”
It only cost me 20 naira
“Ó lè máa ná wọn tó ẹgbẹ̀rún dọ́là”
It may cost them up to a thousand dollars
“Ìyá mi ń bá oníkiri ná”
My mother's haggling with the hawker
“Mo ná ọjà Mọ́kọ́lá”
I trade at Mokola market
“Mo na ọwọ́ mi dì í mú”
I stretched out my hand to grasp it
“Àwòdì na ìyẹ́ rẹ̀, kí ó sì fò lọ”
The hawk spread its wings and flew away
“Ọlọ́pàá na ìbọn sí wọn lójú”
The police pointed a gun in their face
Ìpele CEFR
C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free