HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ ìbì | Babel Free

Ọ̀rọ̀-orúkọ CEFR C2
ì.bì

Àwọn ìtumọ̀

  1. pushing, rolling, swaying of something
  2. questioning, question, enquiring
  3. ancestry
  4. birth
  5. this place or location, here
  6. place, locus, location
  7. placenta
  8. evil, wickedness
  9. position, point, degree
  10. misfortune, tragedy
  11. somewhere
  12. reason, on account of, perspective of

Àwọn àpẹẹrẹ

“Ìbì omi òkun”

The rolling of the waves of the ocean

“Ibí l'a gbé sin baba

Here is where we buried the father

Ibi òmíràn-án jẹ́ ilẹ̀ rere; ibi òmíràn-án jẹ́ ilẹ̀ aṣálẹ̀”

Some places have good soil, other places are barren land

Ibi ajá ni a ti ń mọ òkúrorò àpọ́n”

It is from the perspective of the dog that we know of the mean bachelor

“Ijọ́ a bá ríbi ni ibi í wọlẹ̀”

The day we see the placenta is the day we bury it in the ground

“Wọ́n fi ibi san án fún olóore”

They repaid their benefactor with evil

Ibi bá wọ́n”

They encountered great misfortune

Ìpele CEFR

C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
See all C2 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo ìbì tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free