HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ ta | Babel Free

Ọ̀rọ̀-ìṣe CEFR C2

Àwọn ìtumọ̀

  1. to sell something
  2. to grow, to form, to become big
  3. to splash, pop, explode
  4. to spring, burst, bounce
  5. to shine (as in the sun or daylight)
  6. to shoot, fire (from a weapon that releases a projectile).
  7. to stick out visibly, to protrude
  8. to spin something, to roll
  9. to snatch (suddenly)
  10. to flirt, to talk with teasing affection
  11. to oppose or refuse something loudly
  12. to sting
  13. to be spicy, to be hot
  14. to kick
  15. to pick, pluck, floss (as in your teeth)

Àwọn ọ̀rọ̀ tó dọ́gba

English sell
Kurdî şell

Àwọn àpẹẹrẹ

“kí l'a à bá tà k'á fi ra ọmọ?”

what could we possibly have sold to purchase a child?

“uṣu ta, kí uṣu ò ta, ọkọọkan ló gbéṣu àbá mi láti oko rẹ l'Éjìgbò”

If the yam grows big or not, they must carry the yams of my father one by one from his farm in Ejigbo

“gúgúrú ta”

The popcorn popped on the stove

“ìgbìmọ̀ alátakòó ta lórí ọ̀rọ̀ náà”

The opposition opposed the measure very loudly

“oòrún ta sí wá lára”

The has shined on us

“ọlọ́pàá ta ìbọn”

The police officer fired his gun

“oyín ta wọ́n”

The bee stung them

“atá ta”

The pepper was spicy

“ẹṣín ta, ta, ta, ó kú o!”

The horse kicked, kicked, and kicked, and then it died

“ó ń fi wá tayín”

He was deliberately ignoring us at work

“eyín ta síta”

The tooth stuck out

“ó ta òkòtó”

She spun the spinning top

“àṣá idìí ta òròmọdìẹ nílẹ̀”

The hawk snatch a chick from the ground

“àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin ń tage

The young boys and girls were flirting with each other

Ìpele CEFR

C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
See all C2 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo ta tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free