HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ se | Babel Free

Ọ̀rọ̀-ìṣe CEFR C2

Àwọn ìtumọ̀

  1. to break; to snap
  2. to thatch
  3. to be poverty-stricken; to be destitute
  4. to offend
  5. to happen
  6. to originate from; to emerge from
  7. to do
  8. to disturb, affect
  9. to condense
  10. to sieve
  11. to cook
  12. to block; to shut
  13. to sprain
  14. to sin
  15. to manifest; to come to pass
  16. to make
  17. to boil
  18. to miss
  19. to fold
  20. to gush out; to teem out
  21. to curse; to swear

Àwọn àpẹẹrẹ

“Ó se ọbẹ̀ ilá.”

He cooked okra soup.

“Mi ò mọ ẹyin ín sè.”

I don't know how to boil eggs.

“Wọ́n sé fèrèsé náà.”

They blocked that window.

“Òkúta tí ó jù sé ihò.”

The rock she threw missed the hole.

“Mi ò fẹ́ ṣe nǹkan kan

I don't want to do anything

“Wọ́n máa ń fi igi ṣe ilẹ̀kùn”

They usually use wood to make doors

“Àìsàn ń ṣe mí”

Sickness is disturbing me

“Kí l'ó ń ṣe ọ́?”

What's wrong with you?

“Ó fẹsẹ̀ ṣẹ́”

He sprained his leg

“Ikán ń ṣẹ́ láti ilẹ̀ sísán”

Termites are teeming from the cracked earth

“Ọmọlúwàbí kò gbọdọ̀ ṣẹ́ èpè”

A good person mustn't spew curses

“Wọ́n máa ń tún ààfin Ọ̀yọ́ ṣẹ́ lọ́dọọdún Bẹẹrẹ”

The palace of Oyo is rethatched every Beere festival

“Ìṣẹ́ ti ṣẹ́ ọ̀tá wa.”

Poverty has afflicted our enemies.

“O ti ṣẹ̀ wá, o dẹ̀ ti já wa kulẹ̀.”

You have done us wrong and let us down.

“A ò tíì kófá nílẹ̀, gbogbo ẹ̀ ti ń ṣẹ.”

We haven't packed the Ifa divination paraphernalia from the ground, and everything's already manifesting.

Ibo ni wọ́n ti ṣẹ̀ wá?”

Where do they originate from?

Ìpele CEFR

C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
See all C2 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo se tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free