HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ aroko | Babel Free

Ọ̀rọ̀-orúkọ CEFR B1
à.ɾō.kò

Àwọn ìtumọ̀

  1. countryside; rural area
  2. essay
  3. In traditional Yoruba society, a symbolic message sent as a form of communication between two entities. The purpose of the àrokò was to send a secret message in which only the two entities communicating would understand what the contents of the àrokò meant.
  4. symbol, sign

Àwọn ọ̀rọ̀ tó dọ́gba

English essay

Àwọn àpẹẹrẹ

“Tí obìnrin tàbí ọkùnrin bá ránṣẹ́ òòyà bí àrokò sẹ́ni kejì wọn, ó túmọ̀ sí pé wọ́n fẹ́ pínyà ipò tọkọtaya”

If a man or a woman sends a comb as a symbolic message, it means that they intend to separate from their marriage

“Baṣọ̀run Gáà fi ẹyin oódẹ pàrokò ránṣẹ́ sí Aláàfin”

Basorun Gaa used a parrot egg as a symbolic message to the Alaafin.

Ìpele CEFR

B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
See all B1 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo aroko tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free