Meaning of sun | Babel Free
sũ̀Definitions
- to sleep
- to roast
- to save; to conserve; to manage (money; energy)
- to trickle; to flow
- to cry
- to aim; to target
- to shift; to move
- to make a complaint
- to burn; to set on fire
- to chant
- to nudge; to motivate
- to prick
Equivalents
English
move
Examples
“Mo sùn gbalaja”
I slept stretched out
“Mo sun ẹran.”
I roasted the meat.
“A máa ń sun òkú nínú àṣà tèmi.”
We cremate the dead in my culture.
“Àwọn jagunjagun ya wọ̀lú, wọ́n sì dáná sun ojúbọ”
The warriors raided the town and set the shrines on fire
“Wọ́n ń sun ẹkún níbi ìsìnkú”
They're crying at the burial ground
“Ọdẹ ni ó máa ń sun ìjálá, ìyàwó ni ó máa ń sun ẹkún-ìyàwó”
Hunters chant ìjálá, and brides chant the ẹkún-ìyàwó
“Ìyẹn ni mò ń fojú sùn lọ́dún tó ń bọ̀”
That's what I aspire for this coming year
“Sún mọ́ mi.”
Move closer to me.
“Pẹ̀lúmi fẹ́ sún ìpàdé síwájú”
Pelumi wants to postpone the meeting
“Ó sún mi láti wọ́de”
It motivated me to protest
“Ẹ̀gún sún mi lọ́wọ́”
The thorn pricked me
“A ti fẹjọ́ yín sùn wọ́n”
We have reported you to them
“Inez sọ pé: “A kọ́ wọn láti máa bójú tó ilé, láti máa ṣún nǹkan lò, àti láti máa tọ́jú aṣọ ara wọn.”
Says Inez: “We taught them to care for the home, to be economical, and to care for their own clothes.
CEFR level
C2
Mastery
This word is part of the CEFR C2 vocabulary — mastery level.
This word is part of the CEFR C2 vocabulary — mastery level.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free