Meaning of sọgbodile sọgbẹdigboro | Babel Free
sɔ̄.ɡ͡bó.dī.lé sɔ̀.ɡ͡bɛ́.dì.ɡ͡bō.ɾōDefinitions
development (in rural areas or at the fringes of urban areas); urban sprawl
Examples
“Àtẹ̀jáde kan tí Àjọ Ìparapọ̀ Àwọn Orílẹ̀-Èdè fi ṣọwọ́ sáwọn oníròyìn sọ pé: “Nítorí iṣẹ́ àgbẹ̀, iṣẹ́ sọgbódilé-sọ̀gbẹ́dìgboro àtàwọn ìgbòkègbodò míì téèyàn ò lè tètè rí ipa wọn, àwọn igbó kìjikìji tó kù sórí àwọn òkè kan ti ń pa run.””
“Some of these last wild areas are fast disappearing in the face of agriculture, infrastructure development and other creeping impacts,” explains a recent United Nations press release.
CEFR level
B2
Upper Intermediate
This word is part of the CEFR B2 vocabulary — upper intermediate level.
This word is part of the CEFR B2 vocabulary — upper intermediate level.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free