Meaning of pa | Babel Free
k͡pāDefinitions
- to kill
- to tell, to convey
- to rub
- to gain, to make
- to be in a state, defined by a following adverb
- to be tight
- to be bald
- to murder
- to scorch, to drench, to beat usually in relation to weather
- to earn (money)
- to execute
- to switch off, to turn off
- to extinguish
- to stop, to terminate
- to pain, to kill
- to disturb
- to intoxicate
- to open, to smash open, to thresh
- to hatch
Examples
“Ẹ fẹ́ pa mí ni!?”
You want to kill me!?
“Ó pa ìyàwó ẹ̀.”
He murdered his wife.
“Má gbàgbé láti máa pa tẹlifíṣọ̀n.”
Don't forget to turn off the television.
“A dúpẹ́ pé wọ́n pa iná kó tó jó odindi ilé tán pátá.”
Thankfully the fire was extinguished before it burnt the whole house down.
“Wọ́n pa ìlù.”
They stopped the drumming.
“Yéè! Ẹsẹ̀ yìí fẹ́ pa mí o!”
Ouch! My feet are killing me!
“Ebi ń pa mí.”
Hunger is disturbing me.
“Ọtí ń pa wọ́n.”
Alchohol is intoxicating them.
“Ẹ bá mi pa obì yìí.”
Help me open this kola nut.
“Ó pa ọkà.”
He threshed the corn.
“Adìyẹ mi ti pa ọmọ”
My hen's hatched chicks
“Irọ́ l'o ń pa o!”
You're telling a lie!
“Mo máa ń fi òrí pa ọwọ́ mi”
I use shea butter to moisturize my hands
“Òjò ń pa mí.”
Rain is drenching me.
“Òjò ń pa òrùlé.”
The rain is beating the roof.
“Oòrùn ń pa mí.”
The sun is beating me.
“Wọn kì í pa owó látinú iṣẹ́ yìí.”
They don't make money from doing such work.
“Ọbẹ̀ tó dùn, owó ló pa á”
A delicious stew; money is what earnt it
“Òkun pa rọ́rọ́.”
The sea is calm.
“Mo dè é pa”
I screwed it tight
“Ó pá lórí.”
He's bald on the head.
“(He is bald)”
CEFR level
C2
Mastery
This word is part of the CEFR C2 vocabulary — mastery level.
This word is part of the CEFR C2 vocabulary — mastery level.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free