Meaning of atẹjiṣẹ | Babel Free
à.tɛ̀.d͡ʒí.ʃɛ́Definitions
text message
neologism
Examples
“Àtẹ̀jíṣé tí a sẹ̀sẹ̀ gbà láti ọwọ́ ọmọ Nàìjíríà rere kan fi yé wa pé súnkẹrẹrẹ-fàkẹrẹrẹ ọkọ̀ wà láti Ajégúnlẹ̀ sí Mile Two pọ̀ díẹ̀ nítorí òjò tí ó rọ̀.”
The text message we have just received from a good citizen of Nigeria informed us that there was a serious traffic jam from Ajégúnlẹ̀ to Mile Two because of the rain.
CEFR level
B1
Intermediate
This word is part of the CEFR B1 vocabulary — intermediate level.
This word is part of the CEFR B1 vocabulary — intermediate level.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free