Meaning of agbẹ́gilére | Babel Free
ā.ɡ͡bɛ́.ɡī.lé.ɾēDefinitions
woodcarver
Examples
“Bísí Fakẹ́yẹ jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká agbẹ́gilére, ó wá láti ìdílé agbẹ́gilére tí ó gbajúmọ̀. Bàbá-bàbá-bàbá rẹ̀ ni agbẹ́gilére Ọláwọyin láti Ìlá Ọ̀ràngún. Ìbátan Lámìdí Fákẹ́yẹ ni ó jẹ́. Àwọn ẹbí Fákẹ́yẹ ti gbé àwọn ìṣe àdáyébá ère gbígbẹ́ ilẹ̀ Yorùbá ga, wọn sì ti sọ ìṣe náà ti gbajúgba dé òkè òkun.”
Bisi Fakeye is a carver of renown, from a family of famous carvers. His great grandfather was the carver Olawoyin from Ila Orangun. He is cousin to Lamidi Fakeye. The Fakeye family have maintained and developed the carving traditions of the Yoruba people and given them international fame.
CEFR level
C1
Advanced
This word is part of the CEFR C1 vocabulary — advanced level.
This word is part of the CEFR C1 vocabulary — advanced level.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free