HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ ogidigbo | Babel Free

Ọ̀rọ̀-orúkọ CEFR B2
ò.ɡì.dì.ɡ͡bó

Àwọn ìtumọ̀

  1. A Yoruba drum belonging to the gbẹ̀du class of drums, it is used to make coded messages or send long-distance messages. It was mainly played in the royal court of the Aláàfin.
  2. crowd

Àwọn àpẹẹrẹ

“bí òwe, bí òwe, ni à ń lu ìlù ògìdìgbó, ọlọ́gbọ́n níí jó o, ọ̀mọ̀ràn níí sìí mọ̀ ọ́n”

the ògìdìgbó drum is beaten in drum beats like proverbs, it is the wise who dance to its rhythm correctly, and only the wise can understand or decode it

“àwọn ògìdìgbó ènìyàn-án wà níbẹ̀”

There was a crowd of people there

Ìpele CEFR

B2
Aàrin gíga
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B2 — ìpele aàrin gíga.
See all B2 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo ogidigbo tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free