HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ iborun | Babel Free

Ọ̀rọ̀-orúkọ CEFR B1
ì.bō.ɾũ̀

Àwọn ìtumọ̀

shawl; a shoulder sash worn by women

Àwọn àpẹẹrẹ

“fi ìborùn kọ́ èjìká”

to put a shawl on one's shoulder

“Fún òde pàtàkì, obìnrin Yorùbá gbọ́dọ̀ ró ìró, ó gbọ́dọ̀ wọ bùbá, ó gbọ́dọ̀ we gèlè, ó sì gbọ́dọ̀ fi ìboorùn kọ́ èjìká. Bi òde yìí kì í bá ṣe òde pàtàkì, obìnrin lè má lo ìboorùn.”

For important occasions, a Yoruba woman must tie a wrapper, wear a blouse, wear a gele, and hang a scarf on her shoulder. If the event is not important, women may not use shawls

Ìpele CEFR

B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
See all B1 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo iborun tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free