Ìtumọ̀ fa | Babel Free
fàÀwọn ìtumọ̀
Àwọn àpẹẹrẹ
“mo fa aṣọ”
I pulled the clothes
“eéwó t'ó wú ti fà”
The boil that was swollen has reduced
“ó fa ìlà sórí ìwé”
He drew a line on the piece of paper
“ọ̀lẹ́ fà tìì lẹ́nu iṣẹ́”
The lazy person was sluggish at work
“ọbẹ̀ ewédú náàá fà”
This ewedu soup is mucilaginous
“bí ìgbín fà, ìkarahun á tẹ̀lé e”
When the snail crawls its shell shall follow it
“ìyà púpọ̀ ni ó fa ẹkún”
Too much suffering is the cause of weeping
“ọkàn àwọn ọmọ́ fà mí”
I longed for those children
“alápatàá fá awọ náà”
The butcher wiped off the skin
“mo fá irun abíyá”
I shaved my armpit hair
Ìpele CEFR
C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free