Ìtumọ̀ eewọ | Babel Free
èè.wɔ̀Àwọn ìtumọ̀
Àwọn àpẹẹrẹ
“Personal taboos are often given to individual people early in life via the Àkọsẹ̀jayé.”
“èèwọ̀ ni kí aboyún rìn ní ọ̀sán gangan”
It is a taboo for a pregnant woman to walk around in the hot afternoon
“àdín jẹ́ èèwọ̀ Èṣù”
Giving the orisha Esu palm kernel oil is a taboo
“èèwọ̀ ni nílẹ̀ Yorùbá, kí ìyàwó titun bá ọkọ ọ rẹ̀ nílé”
It is an abomination in Yorubaland for a new bride to meet her new husband at home when she arrives to her marital home
Ìpele CEFR
B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Wo pẹ̀lú
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free