HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ dumbu | Babel Free

Ọ̀rọ̀-ìṣe CEFR B1
dú.ŋ́.bú

Àwọn ìtumọ̀

to butcher, to slaughter (in particular) in the halal method

transitive

Àwọn àpẹẹrẹ

“Wọ́n máa ń dúḿbú màlúù fọ́dún Iléyá.”

They typically butcher cows for Eid al-Adha.

“A-ṣe-kó-súni, Ìmàle Adọ̀dọ̀/ Ó ní ‘Bí wọn kò dúńbú omi/ Òun kò ní mu!/ Bí wọn kò dúńbú ẹja/ Òun kò ní jẹ!”

One who makes things hard for others, an extremist Muslim/ Who says if water was not slaughtered/ He would not drink!/ If fish was not slaughtered/ He would not eat!

Ìpele CEFR

B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
See all B1 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo dumbu tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free