Ìtumọ̀ dodo | Babel Free
dò.dòÀwọn ìtumọ̀
Àwọn àpẹẹrẹ
“rẹ̀ dòdò”
To turn or become a deep red
“Ara wọn rẹ̀ dòdò bíi ẹ̀jẹ̀.”
Their body turned dark red like blood.
“Àwọn Yorùbá kì í wọ aṣọ tó bá rẹ̀ dòdò.”
The Yoruba do not wear bright red clothes.
“Ó rẹ̀ dòdò bí òòrùn alẹ́.”
It turned deep red like the late evening sun.
“Ó já sí pápá, ó rẹ̀ dòdò, ó so igba àdó mọ́rí.”
It bursts into the open field, it comes out in deep red, it ties two hundred tiny gourds on its head (riddle = imí/ìgbẹ́ (feces))
“Ìlẹ̀pa dòdò kì í jẹ́ kí òkú bẹ̀nìyàn wò.”
The deep red laterite from fresh grave does not allow the dead to come and visit his relations.
“12: Ojú rẹ̀ yóò rẹ̀ dòdò ju wáìnì lọ.”
12: His eyes will become redder than wine.
“dín dòdò”
to fry plantain
“Dòdò díndín kò ṣòro rárá.”
Frying plantain isn't hard at all.
“Oúnjẹ tí mo fẹ́ràn ju ni dòdò. Oúnjẹ díndín ni dòdò. Dòdò kò ṣòro láti dín rárá.”
My favorite food is fried plantain. It's a fried food. (Fried) Plantain isn't hard to fry at all.
Ìpele CEFR
B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free