HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ de | Babel Free

Ọ̀rọ̀-ìṣe CEFR C2

Àwọn ìtumọ̀

  1. to be soft or tender in texture
  2. to hunt; to set a trap
  3. to tie down, to constrain
  4. to deputize, to hold a position for someone temporarily
  5. to await, to wait for
  6. to arrive
  7. to cover, to wear a hat
  8. to be stupid or foolish; (literally) to have a soft head (indicating that one has no brain)
  9. to become a skillful hunter
  10. to embroider
  11. to attain, to reach a particular point
  12. to become reduced or weakened in degree or intensity
  13. to become comfortable or relaxed

Àwọn àpẹẹrẹ

“Mo dè é lọ́wọ́ àti lẹ́sẹ̀”

I tied him on both his hands and legs

“Mo de ọrùn aṣọ náà”

I embroided the neck of the clothes

“Ó ń de ipò fún mi”

He was deputizing my position for me

“Mo jókòó dè é”

I sat down and waited for him

“A ti dé”

We have arrived

“ọsàn yìí ti dẹ̀”

This orange has become soft

“ọmọ́ dẹ́”

The child is foolish

“ibà mi ti dẹ̀”

My fever has reduced in intensity

“Mo dẹ ìgèrè láti pẹja”

I set a metal fish trap to kill fish

Ìpele CEFR

C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
See all C2 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo de tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free