Ìtumọ̀ biliọnu | Babel Free
bí.lí.ɔ̀.nùÀwọn ìtumọ̀
Àwọn àpẹẹrẹ
“Ní ọjọ́ karùn-ún-dínlógún oṣù Bélú, ọdún 2022 ni Àjọ Ìṣọ̀kan Àgbáyé sọ pé àwọn olùgbé àgbáyé ti tó bílíọ̀nù mẹ́jọ.”
It was on November 15, 2022 that the United Nations stated that the world's population has reached 8 billion.
“Oyetola tún ní yàtọ̀ sí bílíọ̀nù mẹ́rìnlá náírà tí àwọn fi kalẹ̀ sápò ìjọba, bílíọ̀nù mẹ́jọ náírà mìíràn yóò tún wọ àpò ìjọba láàárín oṣù kejìlá sí oṣù kìíní ọdún tó ń bọ̀.”
Oyetola also said that apart from the 14 billion naira that they put down into the [next] government's accounts, another 8 billion will enter the government's accounts between next December and next January.
Ìpele CEFR
B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free