Ìtumọ̀ ba | Babel Free
bàÀwọn ìtumọ̀
- to ferment
- to plant seeds in prepared pots for future transplanting into a farm (when it becomes an established seedling)
- to press a wound; to apply a warm compress on a wound
- to hit (with an impact)
- to carry out the process of fermentation on seeds or plants
- to be overcome with fear (literally, to be hit with fear)
- to be too long or oversized (to hit the ground)
- to perch
- to braid; to plait
Àwọn ọ̀rọ̀ tó dọ́gba
English
Ferment
Àwọn àpẹẹrẹ
“kòkó ti bà”
The cocoa seeds have fermented
“ba òrom̀bó”
To plant lemon seeds for future transplanting
“ba ojú egbò”
To apply a warm compress to a wound
“ọfà á bà wọ́n”
The arrow hit them
“ẹ̀rú bà wá”
Fear overcame us
“agbádá yìí bà mí nílẹ̀”
The agbada was too big for me
“Lékeléke bà mí lékè, ẹyẹ àdàbà bà mí lékè”
An egret perched on me, a dove perched on me
Ìpele CEFR
C2
Ọ̀gá pípé
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C2 — ìpele ọ̀gá pípé.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free