HomeServicesBlogDictionariesContactSpanish Course
← Padà sí ìwáàrí

Ìtumọ̀ agbẹ́gilére | Babel Free

Ọ̀rọ̀-orúkọ CEFR C1
ā.ɡ͡bɛ́.ɡī.lé.ɾē

Àwọn ìtumọ̀

woodcarver

Àwọn àpẹẹrẹ

“Bísí Fakẹ́yẹ jẹ́ ìlúmọ̀ọ́ká agbẹ́gilére, ó wá láti ìdílé agbẹ́gilére tí ó gbajúmọ̀. Bàbá-bàbá-bàbá rẹ̀ ni agbẹ́gilére Ọláwọyin láti Ìlá Ọ̀ràngún. Ìbátan Lámìdí Fákẹ́yẹ ni ó jẹ́. Àwọn ẹbí Fákẹ́yẹ ti gbé àwọn ìṣe àdáyébá ère gbígbẹ́ ilẹ̀ Yorùbá ga, wọn sì ti sọ ìṣe náà ti gbajúgba dé òkè òkun.”

Bisi Fakeye is a carver of renown, from a family of famous carvers. His great grandfather was the carver Olawoyin from Ila Orangun. He is cousin to Lamidi Fakeye. The Fakeye family have maintained and developed the carving traditions of the Yoruba people and given them international fame.

Ìpele CEFR

C1
Onígbalárugẹ
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR C1 — ìpele onígbalárugẹ.
See all C1 Yorùbá words →

Wo pẹ̀lú

Kọ́ ọ̀rọ̀ yìí nínú àyíká-ọ̀rọ̀

Wo agbẹ́gilére tí a lò nínú ìjíròrò gidi nínú ẹ̀kọ́ èdè ọ̀fẹ́ wa.

Bẹ̀rẹ̀ Ẹ̀kọ́ Ọ̀fẹ́

Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free