Ìtumọ̀ ọdun | Babel Free
ɔ̀.dũ̀Àwọn àpẹẹrẹ
“ọdún ó yabo o!”
May the year be a favorable one!
“wọ́n máa ń ṣe ọdún Igogo nílùú Ọ̀wọ̀ lọ́dọọdún láti ṣe ìrántí òrìṣà Ọ̀rọnṣẹ̀n tó jẹ́ aya Ọlọ́wọ̀ Rẹ̀nrẹ̀ngẹnjẹ̀n nígbà ìwásẹ̀”
They hold the Igogo festival every year in remembrance of the deity Oronsen, who was the wife of King Renrengenjen in the past
Ìpele CEFR
B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free