Ìtumọ̀ ọ̀bọ | Babel Free
ɔ̀.bɔ̀Àwọn ìtumọ̀
Àwọn ọ̀rọ̀ tó dọ́gba
English
monkey
Àwọn àpẹẹrẹ
“Ọ̀bọ mẹ́tàléláàádóje (133) ni ó wà nínú ọgbà ẹranko yìí.”
There are 133 monkeys in this zoo.
“Kò sí ohun tí ìnàkí fi ṣe orí tí ọ̀bọ kò fi ṣe orí.”
A baboon or chimpanzee's head is not different from a monkey's head. (proverb on equality)
“Ọ̀bọ ni wọ́n.”
They're fools.
“Ọlọ́run nìkan ṣoṣo l'ó gbọ́n, ọ̀bọ lènìyàn.”
It is only God who is wise, a human creature is a fool. (proverb on divine wisdom)
Ìpele CEFR
B1
Aàrin
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Ọ̀rọ̀ yìí jẹ́ ara àkójọ-ọ̀rọ̀ CEFR B1 — ìpele aàrin.
Wo pẹ̀lú
Know this word better than we do? Language is a living thing — help us keep it growing. Collaborate with Babel Free